Fight For You byAdekunle Gold

Hello Sweety! Don't cry; don't cry; Wipe your tears Awelewa, ma a worry; I go take you go O Pretty baby; don't cry; big girls no dey cry {no dey cry} Awelewa, ma a worry; you go follow me go Bobo to fe e s'ile, se b'o se n se e ni yi o? Eni l'ori o ni fila; se b'o se n t'oju e ni yi o?
Make I Fight For You; now, now, now; Ololufe o {Je n jaa fun e o} Ayaba ki n sun 'kun {ahhh}; Ayaba ki n j'iya a {ahhhhh} (Je n jaa fun e o) You supposed dey happy {ahhh}; You supposed dey laugh o {ahhhhh} (Je n jaa fun e o) Je n jaa fun e o {ahhh}; jaa fun e; Oh baby o {ahhhhh} (Je n jaa fun e o)
T'oba je Mike Tyson ni, mo ni size e l'owo T'owo mi o ba ka, mo ni Bajinotu n'ile o Bobo to fe e s'ile, se b'o se n se e ni yi o? Eni l'ori o ni fila; se b'o se n t'oju e ni yi o?
Oleremi; make I Fight For You; now, now, now; Ololufe o {Je n jaa fun e o} Ayaba ki n sun 'kun {ahhh}; Ayaba ki n j'iya a {ahhhhh} (Je n jaa fun e o) You supposed dey happy {ahhh}; You supposed dey laugh o {ahhhhh} {Je n jaa fun e o} Je n jaa fun e o {ahhh}; jaa fun e; Oh baby o {ahhhhh} (Je n jaa fun e o)
Ahh; ahhhh; ahhh; ahhhhh; Ah, ah, ah, ah, ah, ahh Make I Fight For You o; O le f'eyin ti, f'eyin ti mi o Awelewa; s'o gbo? (s'o gbo? s'o gbo? s'o gbo?)
Yeh; ohh; yeh, ehh; ohh Make I Fight For Youuu (oh, oh, ohhhhhhhhh) Je n jaa fun e o (Oh, oh, ohhhhhhhhh) Awelewa (Ayaba, Ayabaa) {Oh, oh, ohhhhhhhhh} {Je n jaa fun e o} {Oh, oh, ohhhhhhhhh} Make I; Make I Fight For You Nah, nah, nah, nah; nahh {oh, ohhhh} Je n jaa fun e o} (Oh, oh, ohhhhhhhhh) You supposed dey happy o; eh, eh, ehh (Oohhhhhhhhh) Ayaba, Ayabaa Je n jaa fun e o (Oh, oh, ohhhhhhhhh) Awelewa, ahh; ahh; s'o gbo o? {Oohhhhhhhhh} Je n jaa fun e o (Oh, oh, ohhhhhhhhh) Oh, oh, oh, oh, ohhh (Ayaba, Ayaba, Ayabaa) Oh, oh, ohhhhhhhhh Je n jaa fun e o (Oh, oh, ohhhhhhhhh)

Listen to Song